IPAKO ONIPAKO

 Ìpàkọ́ onípàkọ́ làá rí, ẹni ẹlẹ́ni ló ń rí tẹni.


Translation 

We can only see the back of the head of another person, but it's others who see ours.


Wisdom 

This proverb underscores dependency, about our inability to do things without the help of other people.

You have your own BUT and you have to work on it, before condemning and crucifying other

T


AKE NOTE

Iran ogẹdẹ kìí sunkun àti dẹ, a o ni mo inira, ẹkun oṣe àti ibanujẹ kòní jẹ tìwa Laṣẹ Èdùmàrè. ÀMÍN! 


A kú ojúmọ́

Post a Comment

Previous Post Next Post

Contact Form